Omo Ranti o Omo ma gbagbe omo eni ti iwo nse Igbala ni eee asiko imo re tide o Omo magbagbe eleda re Omo ranti Omo ranti ooo omo ma gbagbe omo eni ti iwo nse Igbala ni eee asiko imo re tide o Omo magbagbe eleda re Magbgbe eni ti seda re Ile ti a fi tomo ire ni owo o Omo ti o la farada yoo san eje fatunbotan Igba lodo hun ni laye Agba fere kan odo na o Tara sasa omo lopin re koda Sekia nigba owuro omo Ranti o Omo ma gbagbe omo eni ti iwo nse Igbala ni eee asiko imo re tide o Omo magbagbe eleda re Tanba ba owo wi to ba n warunki Awon agba lomo ta oko agbele tako ta o Sasa lomo ta oko o iwon lomo ton gboran o Omo ma pami to ba se die yoo domo mapara re Oti to jubo lo se yan eyi ofeyan yoya Booba ranti Oniba lo so bai loruko Oun to ba perare Opo omo ti bayelo won ti kasa idakuda Okunrin o le dobale kagba debi obinrin akunle ki enitoju Oro alufansa lenu won Awon omo nibi niran Aye n baje ema sope on dara Ogede n baje ema sope on pon Suuru baba iwa o kiise todo iwo yi mo o Odo aye ti towo bobo kubo afaitan bene ten mami bi erin lokun Omo ti o janu lenu omu to wa n femi famu owo o fe di borokinii lawujo Moto atata ile alara goolu iyebiye lo fera o Ema gbagbe aje iweyin to pelede ijosi iku ojiji dede lo fiyin sere Ma femi e toro fun satani jowo ronu o omo ranti omo ma gbagbe eleda re Be o ba gboro obi o te o tun gbo tolorun Dede iku n be lode iku ma n be lode on polowo eya Daakun egbooro mi keya gbotebi yungba yungba ayiyin ni Ke ma pa obi yin lekun me ma sowon Dagan ale yungba yungba ewu o ba nilara O ni le jakara ore ko tun mu dani Esin to sare irun ni orun gbeyin Ole ririn ajo kotun wa nile o ko ma lo jepe ko ma lo kuku Wa keni koto keji dandan ni Aikawe Aigbeko ofeyege elere egele alera efe Won fe gba okunkun dalagbara koni le lora emi rerara Ayobe a kun ebi Alapata o fe jere re sorun apadi ni ranti eleda re nigva ewe re jesu Feran re nigbati ojo ibi ko tii de Ogo olorun lo je mamaje kesu o yoo subu Fogo olorun han lana gbogbo Maje kohun aye tan o pa ojare Ki lelere eleda re ton pe o Omo pada ba eleda re laja To ba le yii pada ko satunse aye re Egbegbe yoo gba ye re lagbala Ma wobi okunkun to ti worin jina pada o le gba o se kia Edegbede yoo roo o lagbala Ojo iwaju re yoo ma da Ma beru eni Olorun le pa Eni to tooni gba ni o sa waba Edegbede yoo roo lagbala Eto to fisile fun o ju wura iyebiye lo Jesu duro lenu ona on duro on pe o o omo wole wole wole