To ba n rin l'okunkun Ko le mo, afoju ni To ba n jeun eleera Ko le mo, afoju ni To ba r'omoge to rewa eeeh Ko le mo rara Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua To ba n rin l'okunkun To ba n rin l'okunkun ko le mo rara Ko le mo, afoju ni afoju ni To ba n jeun eleera eh Ko le mo, afoju ni afoju ni bawo lo se fe mo To ba r'omoge to rewa eh ah Ko le mo rara agaga eeh Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua Oju L'obara o, okunkun o da Eda mi gbo Etewo adura araye, ka ma f'opa rin Amin o Eniyan buru ninu aye won le pokun meko fun ni beeni aye buru Aye mi d'owo re, ba mi so, mo mi n bebe o aye mi d'owo re o To ba n rin l'okunkun ma je k'omo araye so mi Ko le mo, afoju ni s'okunkun e To ba n jeun eleera Ko le mo, afoju ni To ba r'omoge to rewaa eeeh Ko le mo rara ko le mo rara Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua ma so mi s'okunkun osan o Gbogbo abarapa, e ranti abirun e ma ranti won E ma se'ranlowo, ema di kun won l'eru rara Ti won to won gbe, oro aye kanpa o Ara aye e buru To ba fe ni loju, won a tun f'ata s'enu Aye To ba n rin l'okunkun Ko le mo, afoju ni Bawo lo se femo To ba n jeun eleera Ko le mo, afoju ni At'owuro, at'osan, at'ale To ba r'omoge to rewa eh lo dudu l'oju afoju Ko le mo rara ko le mo o Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua Ma so mi s'okun ooh Oju L'obara o, okunkun o da Eda mi gbo eda mi gbo Etewo adura araye, ka ma f'opa rin unh unh Eniyan buru ninu aye won le pokun meko fun ni eh Aye mi d'owo re, ba mi so, mo mi n bebe o ba mi so o Baba To ba n rin l'okunkun To ba rin l'okunkun Ko le mo, afoju ni Bawo lo se femo To ba n jeun eleera To ba n jeun Ko le mo, afoju ni To ba n jeun alayan To ba r'omoge to rewa eh eeeh Ko le mo rara ko le mo rara Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua Ma so wa s'okun ooh To ba n rin l'okunkun ah ah ah ah Ko le mo, afoju ni Gbogbo abarapa To ba n jeun eleera Ko le mo, afoju ni E toju afoju yin To ba r'omoge to rewa eh Mo nigbagbo pe Ko le mo rara lojo ojo kan Okunkun o da ma so mi s'okun osan Eledua won a l'aju bi ti...