Emi o fe o oluwa, agbara ati apata Iwo ni igbala mi, ilu olodi mi Ile isho mi giga, ti owo ota ko le kan Ofa mi jade wa lati inu omi nla Titi le mi o fe lorolero ni ise Loro lero ati ni ise, loro lero ati ni ise Loro lero ati ni ise, Loro lero ati ni ise Emi o fe o oluwa, iwo ni iranwo mi Emi o gbeke e le igbala owo otun re Iranwo re yo mumi duro shin shin Awon elomiran gbeke won le keke ogun Sugbon emi gbekele lero ni ise Loro lero ati ni ise, loro lero ati ni ise Loro lero ati ni ise, Loro lero ati ni ise Emi o ma yo si oluwa, oba ati ase mi Fibukun fun oluwa, anu re duro titi Ofi ade de mi, o ko mi lonare Ola ati ojo gigun lo jogun fun mi Ope mi yo po loro lero nise Loro lero ati ni ise, loro lero ati ni ise Loro lero ati ni ise, Loro lero ati ni ise