Mo se ba f'olorun agbaye Mo se ba f'olorun t'oni ikawo ohun gbogbo Emi juba f'olorun to da orun at'aye papo To lagbara lo'ori eda gbogbo Mo se ba f'olorun agbaye Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo To lagbara lo'ori eda gbogbo Eniyan meji nbi omo kan soso Okan soso na a ma la won l'ogun gidi Obi le bimo meji k'enu won ma ka won rara Iwo mighty olorun ti ipa re ka gbogbo aye (Iwo lo tobe) Mo se ba f'olorun agbaye Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo To lagbara lo'ori eda gbogbo Won f'eniyan je Baale t'enu re o ka baa Oba n je lori ilu ti ilu o de tori e toro Ginigini ti wu a re wo ti ko r'oju ara re Aye o'niyan orun n wa riri ni oruko re Mo se ba f'olorun agbaye Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo To lagbara lo'ori eda gbogbo Iwo l'olorun Iwo l'oluwa Iwo l'olorun to pe ohun gbogbo wa Oro to lase lori ohun gbogbo to da o pata Eni ti o le mu ko si ninu ise owo re O lagbara lori eda patapata Mo se ba f'olorun agbaye Mo se ba f'olorun ikawo gbogbo Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo To lagbara lo'ori eda gbogbo Mo se ba f'olorun agbaye Mo se ba f'olorun t'oni ikawo ohun gbogbo Mo juba f'olorun to da orun at'aye papo To lagbara lo'ori eda gbogbo Mo se ba oluda nibo lo o le yi aye si Talo to o Talo ju o To ba pase f'ojo ko yi pada Kabiesi tani o bi oo Olorun eran ara Agbara re lo s'edidi ohun gbogbo Iwo to s'oku di iye Eleri idi Sababi orun to gbe aye duro wawa Olodumare Oye k'eda gbogbo beru re Olorun ogo Oye k'eda gbogbo beru re Iwo to ni eemi ati emi inu Ipinlese aye orun wa ni kawo re Baba oo Oye k'eda gbogbo beru re Olodumare Oye k'eda ma wa riri fun Alagbara giga Oye k'eda ma wa riri fun Iwo to le pa to le ji Ototan Sikun aye sikun orun Ta lo le gba lowo re Aaah Oye k'eda ma wa riri fun Olodumare Oye k'eda gbogbo beru re Awimayewun alagbara ju lo Oye k'eda gbogbo beru re Iwo to ni eemi ati emi inu Ipinlese aye orun wa ni kawo re Alagbara oo Oye k'eda gbogbo beru re Olodumare Oye k'eda ma wa riri fun Onise iyanu Oye k'eda ma wa riri fun Iwo to le pa to le ji Ototan Sikun ogbon sikun apadi Nbe lowo re Baba ooo Oye k'eda ma wa riri fun Iba re o Olodumare Ogo ma ni fun oo