Alabo to peye Ohun lo n gbe me ro titi di iwo yi oo eeh Oore ofe ti mo n je Anu ye po lo mu mi yan fa lala Babara l'ore to mu mi ji to mu mi sun Mo gbo ope oore de Aramada l'ore ti mo le gba pa Ti mo le gbese mo la ju mo fi ri Oto l'ore pe mo le je mo le mu Won f'ounje nu mi oo Anu l'ore pe ke mi jade kin wole Alaafia ni So when I put together Oore to se laye mi Yet none stop Mo m'ope wa So when I put together Oore to se laye mi Yet none stop Mo m'ope wa Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo O seun Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo O seun Oya mi le nu o jo mi loju O ka mi laya mi o riru ri Won wa n bere lowo mi Ewo ni mo to la Ewo ni mo je Se t'oro o ye rara Ni ma salaye Baba lo n do that thing for me Mo ma r'anu gba ni Tani iba m'okolo mi tele Anu gba aye mi wo ni Mo m'oore Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo O seun Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo O seun Wo n bere b'omi se de nu agbo Iginle lo je ko s'eni to ye Won fe mo bo re se po lara ope Ko de le ye anybody Asiri ninu eledumare ni Baba lo n gbese owo gbara Lemi se gbohun ope mi soke oo Ohun lo n f'aye mi se glamour Lemi se n mo ope igba gbogbo mi wa (He's doing that thing) Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo O seun Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo Iwo lo n do that thing for me Ti mo fi n dupe lo jojo O seun Jesu ti gbe soke wa n be lowo re Agbe o ga oo Agbe o ga Kristi ti gbe soke wa n be lowo re Agbe o ga o Olorun ife Iwo ti gbe soke wa n be lowo re Agbe o ga oo Agbe o ga Iwo ti gbe soke wa n be lowo re Agbe o ga o Olorun ife Iwo ti gbe soke wa n be lowo re Agbe o ga oo Agbe o ga Iwo ti gbe soke wa n be lowo re Mo gbe o ga ooo Ose Olodumare oo