Kishore Kumar Hits

Tope Alabi - Ise Owo Re текст песни

Исполнитель: Tope Alabi

альбом: Igbowo Eda


Igba to mu ọmọ Israẹli kuro loko eru
A o le sope o mo won a kan okun pupa
Igba ti Danieli ru don ọba lojosi
O kuku mo pe iho Kinihun ni won o so sí
Ọmọ Hébérù mẹta ko won o forí balẹ
Osa ma won juwon sinu ina
Iwo to Pin okun niya, iwo to pa eyin Kinihun mọ
Iwo na lo se kẹrin inu ina ileru ahhh
Ẹrú rẹ na to ba ooo, ọlọrun ogo o
Ẹrú rẹ bami, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru
Ooh oh oh, oh oh oh oh (iṣẹ ọwọ rẹ bami leru o)
Eh eh eh ah, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru (ohun tó mọ, iwo gan gan ni amo mo tan eledumare)
Ooh oh oh, oh oh oh oh
Eh eh eh ah, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru
Igba ti Lazaru s'aisan, won ran se sí ọ oh
A o le pe o mọ pe o la iku lọ ni
Igba ti Abrahamu fe Sarah ni Wundia
O kuku mo pe yo fi ọjọ ogbo won dara ire
Igba to ni k'Abrahamu fi Isaki rúbọ fún ọ oh
Shebi iwo na lo fagbo ẹran dipo ẹran
Iwo ti oji oku Lazaru, iwo to f'ọmọ d'arugbo lola
Iwo to fi ìgbọràn fi agbo ẹran dipo omo
Ẹrú rẹ tó bá, ọlọrun ogo
Ẹrú rẹ bami oo, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru
Ooh oh oh, oh oh oh oh (iṣẹ ọwọ rẹ bami leru o)
Eh eh eh ah, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru (iwọ ti o ni iku ati iye o mọ ra rẹ awa ni o yẹ)
Ooh oh oh, oh oh oh oh (oluda oludi, awogba arun ma gbaje)
Eh eh eh ah, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru (ayiwo ọjọ pada, ohun lo wun o lo'n se)
Igba ti Josẹfu lala ko ba ti ro
A o le pe o mo p'awọn ẹgbọn rẹ yóò se ki ta
Igba t'oba lala eru to wani ti o ro
Okuku mo pe elewon Josẹfu ni yo ti f'ọba
Iwọ naa lo mo pe Josẹfu a pada wa bo gbogbo ebi rẹ
Emi o ri ohun to sẹyìn rẹ ri, aditu ọba ogo
O fi iran hàn Josẹfu o tun mu ọba lala aditu
Iwo to f'lewon se didi Yan ẹrú rẹ tó ba ijinle nla ni o
Ahh ahh, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru
Iṣẹ ọwọ rẹ bami leru
Ooh oh oh, oh oh oh oh (iwọ lo fi òpe damu ọlọgbọn)
Eh eh eh ah, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru (o fi alai lagbara danu alagbara ooo, afori sofa nitori ogo)
Ooh oh oh, oh oh oh oh (mo yan mọ yan ni o)
Eh eh eh ah, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru (to mo yan yan s'aye to yanjú, ọlọrun nla, o bami leru)
O ran Isaiah to Ezekiah lo
Oyeku ni o, o gbeyin boro yo
O gba satani laye nile job, okuku mo pe ilopo lo fi di
Bo ti je gan niyen, asiri lo jẹ
Bó ti rí gan niyen, iwo nijinle o
O gba na eburu fa kayefi ehn ehn ehn (ehn)
O buse gada soro ana di ba mi k'oju to mo (ehn)
Eni Aye sope ko le ṣe to tele (ehn)
O wa ko'le alaruru nibe (ehn)
Eni ore po fún tori ise nijosi o (ehn)
O pada wa d'olota nitori oro (ehn)
Iwo to no opin lati bẹrẹ(ẹrú rẹ bami o)
Eniti o bẹrù rẹ (ẹrú rẹ bami o)
Ohun tó dá ju sòbìyà lo (ẹrú ọwọ rẹ bami leru)
Ooh oh oh, oh oh oh oh (ọlọrun amomo tan)
Eh eh eh ah, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru (kosi amoju lọrọ rẹ o)
Ooh oh oh, oh oh oh oh (iwo gan gan ni ye, olusaju ayé dé)
Eh eh eh ah, iṣẹ ọwọ rẹ bami le ru (ọrọ to wa ka to ma soro)
Ijinlẹ to fi ijinlẹ bora (iṣẹ ọwọ rẹ bami leru)
Kayefi nla to ka ni laya (iṣẹ ọwọ rẹ bami leru)
Awa ri ọlọrun ogo (iṣẹ ọwọ rẹ bami leru)
Àwámárìídìí onise nla (iṣẹ ọwọ rẹ bami leru)
Iṣẹ ọwọ rẹ bami o, iṣẹ ọwọ rẹ bami o, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru (o bami leru ooo)
Ooh oh oh, oh oh oh oh (eleru niwa ni o)
Eh eh eh ah, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru (ẹlẹru nise ni o, iwo leleru loro ẹlẹru le óò)
Ooh oh oh, oh oh oh oh (oloro to po)
Eh eh eh ah, iṣẹ ọwọ rẹ bami leru (ayé ọwọ rẹ orun ikawo, kabiyesi óò)

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители