Kishore Kumar Hits

Tope Alabi - Mo Taka Osi Danu текст песни

Исполнитель: Tope Alabi

альбом: Mori Iyanu


Motaka òsi dànù (mọ taka)
Ẹ'mí taka òsì dànù (mọ taka)
Òsi kó máa yá ilé mí
Ki ń má rín na kàn òsi
Òsi ki ń ṣe òun réré, mọ taka
Mọ taka ìyà dànù (mọ taka)
Èmi taka ìyà dànù (mọ taka)
Ìyà kọ má jẹ mí o
Ki ń má rìn ná jẹ ìyà
Ìyà kí n ṣe omi ọbẹ' o, mọ taka
Ẹni tó fẹ irẹ, kò ná ọwọ
Irẹ wun èmi ní témi
Ayé tí mọ wá, kí má jìyà, ki ń má rìna kàn òsì
Ọlọrun to dà mí, kò dà mí fún ìyà
Ki ń má fí ìyà jẹ 'ra mí
Ìjáde, ìwọlé, àtilọ, àtibó, irẹ re kò má wo tèmi o
Mọ taka òfo dànù (mọ taka)
Èmi taka òfo dànù (mọ taka)
Òfo kò ṣe mí o (kò ṣe mí)
Ki ń má ṣe òfo láyé mí o (ki ń má s'òfo, t tọmọ-tọmọ)
Òfo ki ń ṣẹ òun réré, mọ taka
Òfo àdánù àti òfo orí mí ko, mọ taka ẹ sọnù
Ki ń n má sunkún, ki ń má fí Ìka bonu, ko má bo bàtà òfo sí ilé mí
Ki ń má ká wo lerí, fẹsẹ jan lè, láyé tí mọ wá
Ko mamá péjọ bá mí daro, ko fo má ṣe mí (òfo ki ń ṣe tèmi)
Mọ taka àìsàn dànù (mọ taka), (lórúko Jésù o)
Èmi taka werey dànù (mọ taka)
Àìsàn kò má ṣe mí pa, ki ń má-má lọ sí werey (ko má fí kàn mí)
Àìsàn kin se òun rere, (lórúko Jésù) mo taka

Gbogbo ọjọ' lọ burú, àdúrà lọ ra ìgbà padà
Ki ma s'àìsàn, ká ṣọ bora, òtútù nígbà ọrùn
K'orí mí má ṣe daru, ki ń má yá werey ọ'sán gangan
Kò má sọ mí mọ'lẹ', k'àìsàn má pami sì àyídá laiyé mí (laiyé tí mò wá)
Ema gbàdúrà (e má gbàdúrà o)
Ema gbàdúrà o (e má gbàdúrà o)
Ká má tó shi, ká má jìyà (e má gbàdúrà o)
Ayé burú ma, fi inú to ni (e má gbàdúrà o)
Ẹnì tó sumo ní gangan lè ṣeni (e má gbàdúrà o)
Ìgbà òun lóko ènìyàn lọ ṣeyàn (e má gbàdúrà o)
Ibi ilé ayé lo, kò má ye mí o (e má gbàdúrà o)
Asorowa, ẹ jẹ ká ṣe dada (e má gbàdúrà o)
Ẹniti o fẹ òsì kò má fọwọ fàá òsì (e má gbàdúrà o)
Ke má torí òun ayé ká wá di werey (e má gbàdúrà o)
Ká má fo'wọ ará wá bá ayé ará wá jẹ (e má gbàdúrà o)
Ká má gbèrò òfo s'èniyàn, ko fo má ṣe wá (e má gbàdúrà o)
Torí a óò lè wá nínú ẹsẹ', ẹ gbo (e má gbàdúrà o)
Àní K' ọrẹ ọ'fẹ' o má posí (e má gbàdúrà o)
Ọlọ'run o se ibi, eniyan ni ka bi (e ma gbàdúrà o)
Ẹ má gbàdúrà o (e ma gbàdúrà o)
Ẹ dè má fí ìyè sínú (e má gbàdúrà o)
Ẹ má gbàdúrà o (e má gbàdúrà o)
Ẹ má gbàdúrà o (e má gbàdúrà o)

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители