Kishore Kumar Hits

Yinka Ayefele - My Jesus текст песни

Исполнитель: Yinka Ayefele

альбом: Fresh Glory


Yefele
Come on
On the microphone
Iwọ ní ìwo ní ìwo ní, ìwo ni iwọ ní iwọ ní
Jesu Messiah
Iwo ni ma balo o, Jesu mi
Iwo ni ma balo o, Baba
Iwo nikan ni ma balo o, Iwo Jésù mi
Iwo nikan ni ma balo o, titi ayé mi
Iwo ni ma balo o, Jesu mi
Iwo ni ma balo o, Baba
Iwo nikan ni ma balo o, Iwo Jésù mi
Iwo nikan ni ma balo o, titi ayé mi
Iwo nikan lo laye mi o baba
Iwo nikan ṣoṣo, iwọ nikan ni mo gbẹkẹ mi le
Iwo nikan lo laye mi o
Alàgbà wí é da Messiah
Jésù o
Iwo ni baba to n mu Inu mi dun
Iwo ni bàbá tó sọrọ mi dayo
Iwo ni baba o, ko de dojú timi o
Iwo ni iwo ni ma balo Jésù
Iwo ni ma balo o, Jesu mi
Iwo ni ma balo o, Baba
Iwo nikan ni ma balo o, Iwo Jésù mi
Iwo nikan ni ma balo o, titi ayé mi
Iwo ni ma balo o, Jesu mi
Iwo ni ma balo o, Baba
Iwo nikan ni ma balo o, Iwo Jésù mi
Iwo nikan ni ma balo o, titi ayé mi
Ọlọrun mímọ tí wá bá mi se t'emi o
Ọlọrun olurapada ti wá bá mi se t'emi o
Ọlọrun mímọ tí wá bá mi se t'emi
Ọlọrun Olubukun ti fún mi double portion o
I am a winner, I am a winner
I am a winner in the land mosorire
Yefele
I get mercy, and I get favour
Iwo ni iwọ ní ìwo ni baba ni ma balo
Iwo ni ma balo o, Jesu mi
Iwo ni ma balo o, Baba
Iwo nikan ni ma balo o, Iwo Jésù mi
Iwo nikan ni ma balo o, titi ayé mi
Iwo ni ma balo o, Jesu mi
Iwo ni ma balo o, Baba
Iwo nikan ni ma balo o, Iwo Jésù mi
Iwo nikan ni ma balo o, titi ayé mi
Bíbélì ma lo je ko ye mi, wipe iwo ni answer
Le le le le le le
Eni to ba tún gbójú lé o koni jo'gun ofo rara
Oruko Jesu yi ni mo faramọ
Oruko Jesu yi ni mo gbẹkẹle
Oruko Jesu yi ni numer one
Oruko Jesu yi love you
Iwo nikan ni, iwo nikan ni
Iwo ni ma balo
Iwo ni ma balo
Iwọ ní má balo
Iwo ni ma balo o, Jesu mi
Iwo ni ma balo o, Baba
Iwo nikan ni ma balo o, Iwo Jésù mi
Iwo nikan ni ma balo o, titi ayé mi
Iwo ni ma balo o, Jesu mi
Iwo ni ma balo o, Baba
Iwo nikan ni ma balo o, Iwo Jésù mi
Iwo nikan ni ma balo o, titi ayé mi
Iwo nikan ni ma balo, titi ayé mi Jesu
Báyé fe baye ko
Iwo ni ma balo, yefele
Oya eje a lo
Fresh glory lomo
Ogo Titun, ninu ayé mi
Oya eje a lo

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

9ice

Исполнитель

2Baba

Исполнитель