Kishore Kumar Hits

Haruna Ishola - Mafi Kan Won Wa Ninu Meta текст песни

Исполнитель: Haruna Ishola

альбом: 51 Lex Presents Sule Maito


Mafi Kan Won Wa Ninu meta
Alafia owo pelu omo won dun ni
Mafi Kan Won Wa Ninu meta
Mafi Kan Won Wa Ninu meta
Alafia owo pelu omo won dun ni
Akoko ti aba ti ni alafia
Owo ade bowo de omo ade
Akoko ti aba ti ni alafia o
Owo ade bowo de omo ade
Bi Kan osi ninu meta
Kobosi rara afi ti meta ba pe
Bi Kan osi ninu meta
Kobosi rara afi ti meta ba pe
Iru aye ti kaluku wa
Eteti egbo ge bi won ti je
Alafia ni baba agba
Toye kakoni kowo to de
Alafia ni baba agba
Toye kakoni kowo to de
Omo lo siketa
Gbogbo wa lo ma bimo ye
Mo le tori omo jijo idunu odun kan
Eni bimo ni o jogun aye mon wi
Mafi Kan Won Wa Ninu meta
Mafi Kan Won Wa Ninu meta
Alafia owo pelu omo won dun ni
Kosemani loruko omo omo mo sin omo lafe aye o
Kosemani loruko omo omo
Kosemani loruko omo omo mo sin omo lafe aye
Ejowo bi osomo lewa
Asan ni ki ama puro
Ejowo bi osomo lewa o
Asan ni ki ama puro
Omo eni ni foto eni
Omo eni ni foto eni
Ti aba ma kira lode
Won o ni bere pe owo nko
Won o ni bere pe aso nko
Awon somori wa mi à bere
Wa so wipe se alafia lowa
Ile nko Iyawo nko
Se dada lomo nbe nile
Iyen lomu mi ranti wi pe
Alafia legbon ninu meteta
Owo owo la fin tomo
Ni to o to olomo lojo gun aye
Kosemani loruko omo omo o
Kosemani loruko omo omo mo sin omo lafe aye o
Mamaje apasan oluwa fun wa lomo aridunu lan bebe o
Mamaje apasan oluwa
Mamaje apasan oluwa fun wa lomo aridunu lan bebe o
Omo ti o kawe re koleji ti o deniyan nla ni ko fun wa bi
Omo ti o kawe re koleji ti o deniyan nla ni ko fun wa bi
Omo to ma gbe mama niyi da mama lola lawa ntoro
Abe e oluwa nile aye nbi

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители

Eldee

Исполнитель