Kishore Kumar Hits

Sola Allyson - Ase текст песни

Исполнитель: Sola Allyson

альбом: Im'oore


Baba Ẹ ṣe mọ má dúpẹ' Baba o
Eleruniyin o mo má dúpẹ' ó eh
Baba alabo mi Ẹ ṣe
Tí mo rí, tí mo rí, tí mo rí, tí mo ri
Mo rí, mo rí, mo rí, mo
Mo rí Ire abo yẹn ó
Eleruniyin o mo má dúpẹ' ó eh
Ìfẹ' Rẹ' nìkan ló gbemi ro eh
Baba mo dúpẹ' ore àbò yẹn o
Ìfẹ' Rẹ' nìkan ló gbemi ro eh
Ah mo júbà Ọba tó pami mo
Ẹ má ṣe o
E ibà o
Baba Ẹ ṣe mọ má dúpẹ'
Mo dúpẹ', mo dúpẹ', mo dúpẹ' ó, Baba mi o
Eleruniyin o mo má dúpẹ' ó eh
Baba alabo mi Ẹ ṣe
Tí mo rí, tí mo rí, tí mo rí, tí mo ri
Mo rí, mo rí, mo rí
Mo rí Ire abo yẹn ó
Eleruniyin o mo má dúpẹ' ó eh
Ìfẹ' Rẹ' nìkan ló gbemi ro eh
Ah mo júbà, ah mo júbà, ah ah mo júbà
Ah mo júbà Ọba tó pami mo
Ẹ má ṣe o
Baba Ẹ ṣe mọ má dúpẹ'
Mo dúpẹ', mo dúpẹ', mo dúpẹ' ó, Baba mi o
Eleruniyin o mo má dúpẹ' ó eh
Baba alabo mi Ẹ ṣe
Tí mo rí, tí mo rí, tí mo rí, tí mo ri
Mo rí, mo rí, mo rí
Mo rí Ire abo yẹn ó
Eleruniyin o mo má dúpẹ' ó eh
Ìfẹ' Rẹ' nìkan ló gbemi ro eh
Baba mo dúpẹ' ore abo tó fi bo mi ò
Ìfẹ' Rẹ' nìkan ló gbemi ro eh
Ah mo júbà, ah mo júbà, ah ah ab mo júbà
Ah mo júbà Ọba tó pami mo
Ẹ má ṣe o
Eh Eh Ibà ó

Поcмотреть все песни артиста

Другие альбомы исполнителя

Похожие исполнители