Kilaju Do you want it to be well with you? Do you want to live long? Then honour you fathers and your mothers Which is the first commandment of God with a promise Te ba dele, eba mi ki won n'le Eni rina, ko ma s'i ki won lona Te ba dele, eba mi ki won n'le Eni rina, ko ma s'i ki won lona Owe momo mi ajike, ton gbe lona are onipapa Iya nio j'omo alailara I know ooo Ebi nio p'omo ti o lebi I know ooo Oluwa to fi iya gbemi To fi baba fun mi o saishe Eledua to fi iya gbemi o saishe I know ooo Damuso... Dahunso Eru o bami Mo leni a ngboju le Kuluso (Abiamo) Kuluso (Abiamo) Kuluso (Abiamo feyin so) Ku-yeah-ah Kuluso (Abiamo) Kuluso (Abiamo) Kuluso (Abiamo feyin so) Opelope momo Ola baba ni mo nje I know Opelope momo Ola baba ni mo nje I know Ko je fimi sere Baba ara to moyi omo ni Emi naa m'ba ya 'gboro 'Mba d'omo satani omo lasan Mo lemi naa m'ba ya 'pata 'Mba d'omo satani omo lasan Damuso Damuso Eru o bami (Damuso) Mo leni a ngboju le (Damuso Damuso) Damuso Damuso Eru o bami Mo leni a ngboju le Kuluso (Abiamo) Kuluso (Abiamo) Kuluso (Abiamo feyin so) Ku-yeah-ah Kuluso (Abiamo) Kuluso (Abiamo) Kuluso (Abiamo feyin so) (Abiamo feyin, abiamo feyin so) Kuluso (Abiamo) Ko je fimi sere (Abiamo feyin so) Baba ara to moyi omo ni Kulu-luso (Abiamo) Kuluso (Abiamo)