Ebenezeri wa re oo Nibi ti e ran wa lowo de Ka'ma jo o kayo ka fogo folu Ninu irinkerido mi laye, eh Íwó lo bà mi sé Àlubàríkà lówà mí rí Èmi kó, isé ólórun ní Èwu gbógbó ti mo là kójà Ki mà isé àgbàràmi Àtinudà ti mo di, lo njé ki dupé ore Ebenezeri wa re oo Nibi ti e ran wa lowo de Ka'ma jo o kayo ka fogo folu Ebenezeri wa re oo Ema ma se ese Kima nse nipa agbara Oluwa loni imo ati oye Ogo ti àyé rí ti wón pologo Iré lo bà wà se Orin halleluya, hossana lo gbénu wa kó Ése ibi ti èti béré Esé ibi tí ébà dé Adupé oluwàà Ibi ti emu wa looo Ibasepe oluwaaaa Koti wa niti wa ooo Nibo la ba jasi ooo Amo ni sé yin, àdupé àtun ope da Tori wipe Awo kan gbele kéke Awon kan gbekele éshin Awa ta gbekele ooo Ibi tomu wa de, ibi ogo ni Lase wi pe Orin halleluya Orin hosana ooo Orin ebenezer Hosana lo gbenu wa kan Ekorin ebenezeri Ebenezeri wa re oo Nibi ti e ran wa lowo de Ka'ma jo o kayo ka fogo folu Ese ibi te ti beere Ebenezeri wa re oo Ema ma se ese Kima nse nipa agbara Oluwa loni imo ati oye Ogo ti àyé rí ti wón pologo Iré lo bà wà se Orin halleluya, hossana lo gbénu wa kó Oh oh oh oh Ka pànu po Kàdupe Ooooooooo Kà korin ayo kà mó pé wà Oh oh oh oh Ka pànu po àdupe Ooooooooo Kà korin ayo kà mó pé wà Tori pe Agbón ígbé ibunkun àidiyé lé To fi fun wa a a a La nsé ndupe Oh oh oh oh Ka pànu po Kàdupe Ooooooooo Kà korin ayo kà mó pé wà Oh oh oh oh Ka pànu po Kàdupe Ooooooooo Kà korin ayo kà mó pé wà Agbón ígbé ibunkun àidiyé lé To fi fun wa a a a La nsé ndupe Moni Agbón ígbé ibunkun àidiyé lé To fi fun wa a a a La nsé ndupe Gbo gbo àye mí sóró ogo re Tori abubu tàn oré To se fun mi Oh oh ah eh La se ndupé Ebenezeri wa re oo Nibi ti e ran wa lowo de Ka'ma jo o kayo ka fogo folu Ebenezeri wa re oo Ema ma se ese Kima nse nipa agbara Oluwa loni imo ati oye Ogo ti àyé rí ti wón pologo Iré lo bà wà se Orin halleluya, hossana lo gbénu wa kan